Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Privileges of Saints: Partaking of the divine nature

1 ẹsẹ · 36 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Partaking of the divine nature

  1. Nípa èyí tí ó fi àwọn ìlérí rẹ̀ tí ó tóbi púpọ̀ tí ó ṣe iyebíye fún wa: pé nípa ìwọ̀nyí ni kí ẹ̀yin lè di alábápín nínú àbùdá ti Ọlọ́run, nígbà tí ẹ̀yin bá ti yọ kúrò nínú ìbàjẹ́ tí ó ń bẹ nínú ayé nípa ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́.