Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pride: Scribes
Àwọn ẹsẹ nípa Scribes
Ó sì wí fún wọn nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ pé, “Ẹ ṣọ́ra fun àwọn olùkọ́ òfin tí wọ́n fẹ́ láti máa wọ aṣọ gígùn káàkiri, tí wọ́n sì fẹ́ ìkíni ní ọjà,
àti ibùjókòó ọlá nínú Sinagọgu àti ipò ọlá níbi àsè.