Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pride: Contempt and rejection of God's word and ministers
Àwọn ẹsẹ nípa Contempt and rejection of God's word and ministers
Asariah ọmọ Hoṣaiah àti Johanani ọmọ Karea, àti gbogbo àwọn agbéraga ọkùnrin sọ fún Jeremiah pé, “Ìwọ ń pa irọ́! Olúwa Ọlọ́run wa kò rán ọ láti sọ pé, ‘Ẹ má lọ sí Ejibiti láti ṣàtìpó níbẹ̀.’