Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prayer: Vain repetitions of prayers, to be avoided
Àwọn ẹsẹ nípa Vain repetitions of prayers, to be avoided
Ṣùgbọ́n nígbà ti ẹ̀yin bá ń gbàdúrà, ẹ má ṣe àtúnwí asán bí àwọn aláìkọlà, nítorí wọn rò pé a ó tìtorí ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ gbọ́ tiwọn.