Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prayer: Suitable in affliction

2 ẹsẹ · 120 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Suitable in affliction

  1. Olúwa, wọ́n wá sọ́dọ̀ rẹ nínú ìpọ́njú wọn; nígbà tí ìbáwí rẹ wà lára wọn, wọ́n gbàdúrà kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́.

  2. Inú ẹnikẹ́ni ha bàjẹ́ nínú yín bí? Jẹ́ kí ó gbàdúrà. Inú ẹnikẹ́ni ha dùn? Jẹ́ kí ó kọrin mímọ́.