Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Parents: To train them up for God

2 ẹsẹ · 48 abala

Àwọn ẹsẹ nípa To train them up for God

  1. Tọ́ ọmọdé ní ọ̀nà tí yóò tọ̀: nígbà tí ó bá dàgbà, kì yóò kúrò nínú rẹ̀.

  2. Àti ẹ̀yin baba, ẹ má ṣe mú àwọn ọmọ yín bínú, ṣùgbọ́n ẹ máa tọ́ wọn nínú ẹ̀kọ́ àti ìkìlọ̀ Olúwa.