Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Parents: Wicked children, a cause of grief to

2 ẹsẹ · 48 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Wicked children, a cause of grief to

  1. Àwọn òwe Solomoni. Ọlọ́gbọ́n ọmọ ń mú inú baba rẹ̀ dùn, ṣùgbọ́n aṣiwèrè ọmọ ń ba inú ìyá rẹ̀ jẹ́.

  2. Aṣiwèrè ọmọ mú ìbànújẹ́ bá baba rẹ̀ àti ìkorò fún ẹni tí ó bí i lọ́mọ.