Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Oil: The consolation of the gospel

1 ẹsẹ · 49 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The consolation of the gospel

  1. àti láti pèsè fún àwọn tí inú wọn bàjẹ́ ní Sioni láti dé wọn ládé ẹwà dípò eérú, òróró ayọ̀ dípò ọ̀fọ̀, àti aṣọ ìyìn dípò ìpòrúru ọkàn. A ó sì pè wọ́n ní igi óákù òdodo, irúgbìn Olúwa láti fi ọláńlá rẹ̀ hàn.