Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Offence: Not let their liberty occasion, to others
Àwọn ẹsẹ nípa Not let their liberty occasion, to others
Ṣùgbọ́n ẹ máa kíyèsi ara gidigidi nípa ìlò òmìnira yín kí ẹ má ba à mú kí àwọn arákùnrin mìíràn tí í ṣe onígbàgbọ́, tí ọkàn wọn ṣe aláìlera, ṣubú sínú ẹ̀ṣẹ̀.