Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Offence: Occasions of, forbidden

2 ẹsẹ · 31 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Occasions of, forbidden

  1. Nítorí náà, má ṣe jẹ́ òkúta ìkọ̀sẹ̀ tí ó lè gbé ẹlòmíràn ṣubú ìbá à ṣe Júù tàbí Giriki tàbí ìjọ Ọlọ́run.

  2. Àwa kò sì gbé ohun ìkọ̀sẹ̀ kankan si ọ̀nà ẹnikẹ́ni, ki iṣẹ́ ìránṣẹ́ wa má ṣe di ìsọ̀rọ̀-òdì sí.