Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Offence: Reprove those who cause

2 ẹsẹ · 31 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Reprove those who cause

  1. Mose sọ fún Aaroni pé, “Kí ni àwọn ènìyàn wọ̀nyí ṣe sí ọ, tí ìwọ ṣe mú wọn dá ẹ̀ṣẹ̀ ńlá yìí?”

  2. Bẹ́ẹ̀ kọ́ ẹ̀yin ọmọ mi, nítorí kì ṣe ìròyìn rere èmi gbọ́; ẹ̀yin mú ènìyàn Olúwa dẹ́ṣẹ̀.