Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Obedience to God: Zerubbabel

1 ẹsẹ · 45 abala

Wá "Obedience to God"

Àwọn ẹsẹ nípa Zerubbabel

  1. Nígbà náà ni Serubbabeli ọmọ Ṣealitieli, Joṣua ọmọ Josadaki, olórí àlùfáà pẹ̀lú gbogbo ènìyàn ìyókù, gba ohùn Olúwa Ọlọ́run wọn gbọ́ àti ọ̀rọ̀ wòlíì Hagai, nítorí Olúwa Ọlọ́run ni ó rán an. Àwọn ènìyàn sì bẹ̀rù Olúwa.