Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Obedience to God: To be universal in the latter days

1 ẹsẹ · 45 abala

Àwọn ẹsẹ nípa To be universal in the latter days

  1. Nígbà náà, ni a ó gba ìjọba, agbára àti títóbi ìjọba rẹ̀ ní abẹ́ gbogbo ọ̀run, a ó sì fi fún àwọn ẹni mímọ́, àwọn ènìyàn Ọ̀gá-ògo. Ìjọba rẹ̀ yóò jẹ́ ìjọba títí ayé, gbogbo aláṣẹ ni yóò máa ṣe ìgbọ́ràn sí i, wọn yóò sì máa sìn ín.’