Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Consolation Under Affliction: Christ is the Author and Giver of

3 ẹsẹ · 22 abala

Wá "Consolation Under Affliction"

Àwọn ẹsẹ nípa Christ is the Author and Giver of

  1. láti kéde ọdún ojúrere Olúwa àti ọjọ́ ẹ̀san ti Ọlọ́run wa, láti tu àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀ nínú,

  2. Èmi kò ní fi yín sílẹ̀ láìní Olùtùnú, kí ẹ ma dàbí ọmọ tí kò ní òbí. Rárá o! Mo tún ń tọ̀ yín bọ̀.

  3. Nítorí pé bí àwa ti pín nínú ìjìyà Kristi, gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ nì ìtùnú wa dí púpọ̀ pẹ̀lú nípa Kristi.