Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Andrew: Tells Jesus of the Greeks who sought to see Him

3 ẹsẹ · 10 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Tells Jesus of the Greeks who sought to see Him

  1. Àwọn Giriki kan sì wà nínú àwọn tí ó gòkè wá láti sìn nígbà àjọ,

  2. Àwọn wọ̀nyí ni ó tọ Filipi wá, ẹni tí í ṣe ará Betisaida tí Galili, wọ́n sì ń béèrè lọ́wọ́ rẹ̀, pé, “Alàgbà, àwa ń fẹ́ rí Jesu!”

  3. Filipi wá, ó sì sọ fún Anderu; Anderu àti Filipi wá, wọ́n sì sọ fún Jesu.