Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Altars: Of Reubenites, &c east of Jordan
Àwọn ẹsẹ nípa Of Reubenites, &c east of Jordan
Nígbà tí wọ́n wá dé Geliloti ní ẹ̀bá Jordani ní ilẹ̀ Kenaani, àwọn ẹ̀yà Reubeni, ẹ̀yà Gadi àti ìdajì ẹ̀yà Manase mọ pẹpẹ ńlá tí ó tóbi kan ní ẹ̀bá Jordani.