Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Afflictions: Man is born to 3 ẹsẹ · 21 abala Wá "Afflictions" Gbogbo 106 Tempered with mercy 15 Often severe 14 Frequently terminate in good 8 Exhibit the love and faithfulness of God 7 Of saints, are but temporary 7 Of saints, end in joy and blessedness 7 Sin visited with 7 God appoints 6 God determines the continuance of 5 Consequent upon the fall 4 Of saints, are comparatively light 4 Often arise from the profession of the gospel 4 God dispenses, as He will 3 God regulates the measure of 3 Man is born to 3 Sin produces 3 Always less than we deserve 2 Saints are to expect 2 Saints have joy under 2 God does not willingly send 1 Saints appointed to 1 Fi gbogbo 22 hàn Àwọn ẹsẹ nípa Man is born to Jobu 5:6Bí ìpọ́njú kò bá ti inú erùpẹ̀ jáde wá ni, tí ìyọnu kò ti ilẹ̀ jáde wá.Jobu 5:7Ṣùgbọ́n a bí ènìyàn sínú wàhálà, gẹ́gẹ́ bí ìpẹ́pẹ́ iná ti máa ń ta sókè.Jobu 14:1“Ènìyàn tí a bí nínú obìnrin, ọlọ́jọ́ díẹ̀ ni, ó sì kún fún ìpọ́njú.