Fò sí àkóónú

Tyre

52 verses · 2 known names

A tún mọ̀ ọ́n sí: Tyrus

33.2700, 35.1900 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Tyre

Sẹ́ nípa ìwé
  1. Nígbà tí àwa sì ń wo Saipurọsi lókèèrè, a sì fi í sí ọwọ́ òsì, a fi orí ọ́kọ̀ le Siria, a sì gúnlẹ̀ ni Tire; nítorí níbẹ̀ ni ọkọ̀ yóò tí já ẹrù sílẹ̀.

  2. Nígbà tí a sì ti parí àjò wa láti Tire, àwa dé Pitolemai; nígbà ti a sì kí àwọn ará, a sì bá wọn gbé ní ọjọ́ kan.