Fò sí àkóónú

Bashan

52 verses

32.8000, 35.9300 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Bashan

Sẹ́ nípa ìwé
  1. Ó bá òkun wí, ó sì mú kí ó gbẹ; Ó sìsọ gbogbo odò di gbígbẹ. Baṣani àti Karmeli sì rọ. Ìtànná Lebanoni sì rẹ̀ sílẹ̀.

  2. Hu, igi junifa; nítorí igi kedari ṣubú, nítorí tí a ba àwọn igi tí o lógo jẹ́: hu, ẹ̀yin igi óákù tí Baṣani, nítorí gé igbó àjàrà lulẹ̀.