Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Zoar: King of, fought against Chedorlaomer

2 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa King of, fought against Chedorlaomer

  1. jáde lọ láti bá Bera ọba Sodomu, Birṣa ọba Gomorra, Ṣenabu ọba Adma, Ṣemeberi ọba Seboimu àti ọba Bela (èyí ni Soari) jagun.

  2. Nígbà náà ni ọba Sodomu, ọba Gomorra, ọba Adma, ọba Seboimu àti ọba Bela (èyí ni Soari), kó àwọn ọmọ-ogun wọn, wọ́n sì pa ibùdó ogun wọn sí Àfonífojì Siddimu,