Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Years: (Of visitation,) of severe judgments

2 ẹsẹ · 19 abala

Àwọn ẹsẹ nípa (Of visitation,) of severe judgments

  1. Kò ní ṣẹ́kù ohunkóhun sílẹ̀ fún wọn nítorí èmi yóò mú ibi wá sórí àwọn ènìyàn Anatoti ní ọdún ìbẹ̀wò wọn.’ ”

  2. “Nítorí náà, ọ̀nà wọn yóò di yíyọ́, a ó lé wọn jáde sínú òkùnkùn; níbẹ̀ ni wọn yóò ṣubú. Èmi yóò mú ìdààmú wá sórí wọn, ní ọdún tí a jẹ wọ́n ní ìyà,” ni Olúwa wí.