Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Watchmen: Sounded an alarm at the approach of enemies

2 ẹsẹ · 19 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Sounded an alarm at the approach of enemies

  1. “Ọmọ ènìyàn sọ̀rọ̀ sí àwọn ènìyàn ilẹ̀ rẹ kí ó sì sọ fún wọn: ‘Nígbà tí mo bá fi idà kọlu ilẹ̀ kan, tí àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà yan ọ̀kan lára àwọn ọkùnrin wọn láti jẹ́ alóre wọn,

  2. tí ó sì rí i pé idà ń bọ̀ lórí ilẹ̀ náà, tí ó sì fọn ìpè láti kìlọ̀ fún àwọn ènìyàn,