Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Watchmen: Danger of sleeping on their posts, referred to

2 ẹsẹ · 19 abala

Wá "Watchmen"

Àwọn ẹsẹ nípa Danger of sleeping on their posts, referred to

  1. Wọ́n wí pé, “Ẹ sọ fún àwọn ènìyàn pé, ‘Gbogbo yín sùn nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu wá lóru láti jí òkú rẹ̀.’

  2. Bí Pilatu bá sì mọ̀ nípa rẹ̀, àwa yóò ṣe àlàyé tí yóò tẹ́ ẹ lọ́rùn fún un, tí ọ̀rọ̀ náà kì yóò fi lè kó bá yín.”