Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Watchmen: (Blind,) of careless ministers
Àwọn ẹsẹ nípa (Blind,) of careless ministers
Àwọn olùṣọ́ Israẹli fọ́jú, gbogbo wọn ṣe aláìní ìmọ̀; gbogbo wọn jẹ́ adití ajá, wọn kò lè gbó; wọ́n sùn sílẹ̀ wọ́n ń lálàá, wọ́n fẹ́ràn láti máa sùn.