Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Token: The Passover

1 ẹsẹ · 18 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The Passover

  1. Ṣíṣe èyí yóò wà fún àmì ní ọwọ́ rẹ, àti bí àmì ìrántí ni iwájú orí rẹ, tí yóò máa rán ọ létí òfin Olúwa ní ẹnu rẹ. Nítorí Olúwa mú ọ jáde láti ilẹ̀ Ejibiti pẹ̀lú ọwọ́ agbára ńlá rẹ̀.