Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribes of Israel: Divided on mounts Ebal and Gerizim to hear the law

2 ẹsẹ · 21 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Divided on mounts Ebal and Gerizim to hear the law

  1. Nígbà tí ìwọ bá ti kọjá a Jordani, àwọn ẹ̀yà yìí yóò dúró lórí òkè Gerisimu láti súre fún àwọn ènìyàn: Simeoni, Lefi, Juda, Isakari, Josẹfu àti Benjamini.

  2. Àwọn ẹ̀yà yìí yóò dúró lórí òkè Ebali láti gé ègún: Reubeni, Gadi, àti Aṣeri, àti Sebuluni, Dani, àti Naftali.