Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Gad: The rear of second division of Israel in their journeys

3 ẹsẹ · 25 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The rear of second division of Israel in their journeys

  1. Àwọn ìpín ti ibùdó ti Reubeni ló gbéra tẹ̀lé wọn, lábẹ́ ọ̀págun wọn. Elisuri ọmọ Ṣedeuri ni ọ̀gágun wọn.

  2. Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Simeoni.

  3. Eliasafu ọmọ Deueli ni ọ̀gágun ìpín ti ẹ̀yà Gadi.