Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Gad: Families of
Àwọn ẹsẹ nípa Families of
Àwọn ọmọ Gadi bí ìdílé wọn: ti Sefoni, ìdílé Sefoni; ti Haggi, ìdílé Haggi; ti Ṣuni, ìdílé Ṣuni;
ti Osni, ìdílé Osni; ti Eri, ìdílé Eri;
ti Arodi, ìdílé Arodi; ti Areli, ìdílé Areli.