Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Promises of God: Given to those who believe
Àwọn ẹsẹ nípa Given to those who believe
Ṣùgbọ́n ìwé mímọ́ ti fi yé wa pé gbogbo ènìyàn ni ń bẹ lábẹ́ ìdè ẹ̀ṣẹ̀, kí a lè fi ìlérí nípa ìgbàgbọ́ nínú Jesu Kristi fún àwọn tí ó gbàgbọ́.