Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Promises of God: Preservation in affliction

1 ẹsẹ · 57 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Preservation in affliction

  1. Nígbà tí ìwọ bá ń la omi kọjá, Èmi yóò wà pẹ̀lú rẹ; àti nígbà tí ìwọ bá ń la odò kọjá wọn kì yóò bò ọ́ mọ́lẹ̀. Nígbà tí ìwọ bá la iná kọjá, kò ní jó ọ; ahọ́n iná kò ní jó ọ lára.