Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Miracles of Christ: Lepers cleansed

2 ẹsẹ · 30 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Lepers cleansed

  1. Jesu sì nà ọwọ́ rẹ̀, ó fi bà á, ó wí pé, “Mo fẹ́, ìwọ di mímọ́.” Lójúkan náà, ẹ̀tẹ̀ rẹ̀ sì mọ́!

  2. Nígbà tí ó rí wọn, ó wí fún wọn pé, “Ẹ lọ í fi ara yín hàn fún àwọn àlùfáà.” Ó sì ṣe, bí wọ́n ti ń lọ, wọ́n sì di mímọ́.