Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Miracles of Christ: Peter walking on the sea

1 ẹsẹ · 30 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Peter walking on the sea

  1. Jesu dá a lóhùn pé, “Ó dára, máa bọ̀ wá.” Nígbà náà ni Peteru sọ̀kalẹ̀ láti inú ọkọ̀. Ó ń rìn lórí omi lọ sí ìhà ọ̀dọ̀ Jesu.