Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Ishmaelites: Heads of tribes
Àwọn ẹsẹ nípa Heads of tribes
Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Iṣmaeli bí a ṣe bí wọn, bẹ̀rẹ̀ láti orí: Nebaioti àkọ́bí, Kedari, Adbeeli, Mibsamu,
Miṣima, Duma, Massa,
Hadadi, Tema, Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema.
Èyí ni àwọn ọmọ náà: Nebaioti àkọ́bí Iṣmaeli: Kedari, Adbeeli, Mibsamu,
Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema,
Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Iṣmaeli.