Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The First Temple: Its magnificence

2 ẹsẹ · 72 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Its magnificence

  1. “Ilé Olúwa tí èmi yóò kọ́ yóò tóbi, nítorí pé Ọlọ́run wa tóbi ju gbogbo àwọn ọlọ́run mìíràn lọ.

  2. Láti pèsè ọ̀pọ̀ igi rírẹ́ fún mi, nítorí ilé Olúwa tí mo kọ́ gbọdọ̀ tóbi kí o sì lógo púpọ̀.