Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The First Temple: Cedar of, carved with flowers, &c
Àwọn ẹsẹ nípa Cedar of, carved with flowers, &c
Inú ilé náà sì jẹ́ kedari, wọ́n ṣe iṣẹ́ ọnà rẹ̀ pẹ̀lú ìrudí àti ìtànná. Gbogbo rẹ̀ sì jẹ́ kedari; a kò sì rí òkúta kan níbẹ̀.