Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The First Temple: The floor and walls of, covered with cedar and fir wood
Àwọn ẹsẹ nípa The floor and walls of, covered with cedar and fir wood
Ó sì fi pákó kedari tẹ́ ògiri ilé náà nínú, láti ilẹ̀ ilé náà dé àjà rẹ̀, ó fi igi bò wọ́n nínú, ó sì fi pákó firi tẹ́ ilẹ̀ ilé náà.