Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The First Temple: Had door posts of olive wood carved and gilded
Àwọn ẹsẹ nípa Had door posts of olive wood carved and gilded
Bẹ́ẹ̀ ni ó sì ṣe òpó igi olifi onígun mẹ́rin fún ìlẹ̀kùn ilé náà.
Ó tẹ́ àjà ilé náà pẹ̀lú ìtí igi àti ìlẹ̀kùn ògiri àti àwọn ìlẹ̀kùn ilé Olúwa pẹ̀lú wúrà, ó sì gbẹ́ àwòrán kérúbù sára ògiri.