Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The First Temple: House of the God of Jacob

1 ẹsẹ · 72 abala

Àwọn ẹsẹ nípa House of the God of Jacob

  1. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni yóò wá, wọn yóò sì wí pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á gòkè ńlá Olúwa, àti sí ilé Ọlọ́run Jakọbu. Òun yóò kọ́ wa ní ọ̀nà rẹ̀, kí àwa kí ó lè rìn ní ọ̀nà rẹ̀.” Òfin yóò jáde láti Sioni wá, àti ọ̀rọ̀ Olúwa láti Jerusalẹmu.