Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Seeking God: None, by nature, are found to be engaged in
Àwọn ẹsẹ nípa None, by nature, are found to be engaged in
Olúwa sì bojú wolẹ̀ láti ọ̀run wá lórí àwọn ọmọ ènìyàn bóyá ó le rí ẹni tí òye yé, ẹnikẹ́ni tó ń wá Ọlọ́run.
Ẹ̀mí sá à ju oúnjẹ lọ, ara sì ju aṣọ lọ.
Nítorí gbogbo nǹkan wọ̀nyí ni àwọn orílẹ̀-èdè ayé ń wá kiri. Baba yín sì mọ̀ pé, ẹ̀yin ń fẹ́ nǹkan wọ̀nyí.
kò sí ẹni tí òye yé, kò sí ẹni tí ó ń wá Ọlọ́run.