Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Seeking God: In the day of trouble
Àwọn ẹsẹ nípa In the day of trouble
Nígbà tí mo wà nínú ìpọ́njú, mo wá Olúwa; ní òru ni mo na ọwọ́ mi jáde ní àìkáárẹ̀ ọkàn mí sì kọ̀ láti tù ú nínú.