Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Seeking God: His face
Àwọn ẹsẹ nípa His face
Ọkàn mi wí pé, “Wá ojú u rẹ̀!” Ojú rẹ, Olúwa, ni ti èmí ń wá.
Wá Olúwa àti ipá rẹ̀; wa ojú rẹ̀ nígbà gbogbo.