Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Seeking God: Afflictions designed to lead to
Àwọn ẹsẹ nípa Afflictions designed to lead to
O fi òpin sí ayé wọn nínú asán àti ọdún wọn nínú ìpayà.
Nígbàkígbà tí Ọlọ́run bá pa wọ́n, wọn yóò wá a kiri; wọn yóò fi ìtara yípadà sí i.
Nígbà náà ni èmi ó padà lọ sí ààyè mi títí di ìgbà tí wọn ó fi gbà pé àwọn jẹ̀bi wọn yóò sì wá ojú mi nínú ìpọ́njú wọn, wọn ó fi ìtara wá mi.”