Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Scribes: Their manner of teaching contrasting with that of Christ

2 ẹsẹ · 27 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Their manner of teaching contrasting with that of Christ

  1. nítorí ó ń kọ́ wọn bí ẹni tí ó ní àṣẹ, kì í ṣe bí i ti olùkọ́ òfin wọn.

  2. Ẹnu sì ya ìjọ ènìyàn nítorí ìkọ́ni rẹ̀, nítorí pé ó ń kọ́ni bí ẹni tí ó ní àṣẹ, kì í ṣe bí àwọn olùkọ́ òfin ṣe ń kọ́ àwọn ènìyàn.