Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Scribes: Illustrated of well instructed ministers of the gospel

1 ẹsẹ · 27 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Illustrated of well instructed ministers of the gospel

  1. Ó wí fún wọn pé, “Nítorí náà ni olúkúlùkù olùkọ́ òfin tí ó ti di ọmọ-ẹ̀yìn ní ìjọba ọ̀run ṣe dàbí ọkùnrin kan tí í ṣe baálé ilé, tí ó mú ìṣúra tuntun àti èyí tí ó ti gbó jáde láti inú yàrá ìṣúra rẹ̀.”