Hammath
A tún mọ̀ ọ́n sí: Hemath
33.1200, 35.1600 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Hammath
Àwọn ìlú olódi sì Siddimu, Seri, Hamati, Rakàti, Kinnereti,
àti àwọn ìdílé àwọn akọ̀wé, ẹni tí ń gbé ní Jabesi: àti àwọn ọmọ Tirati àti àwọn ará Ṣimeati àti àwọn ará Sukati. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ará Keni, ẹni tí ó wá láti ọ̀dọ̀ Hamati, baba ilé Rekabu.