Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salah: Called also Sala and Shelah. Son of Arphaxad and ancestor of Joseph.

8 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Called also Sala and Shelah. Son of Arphaxad and ancestor of Joseph.

  1. Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.

  2. Nígbà tí Arfakṣadi pé ọdún márùndínlógójì ni ó bí Ṣela.

  3. Arfakṣadi sì wà láààyè fún ọdún mẹ́tàlénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Ṣela, ó sì bí àwọn ọmọbìnrin àti àwọn ọmọkùnrin mìíràn.

  4. Nígbà tí Ṣela pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Eberi.

  5. Ṣela sì wà láààyè fún ọdún mẹ́tàlénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Eberi tán, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

  6. Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.

  7. Ṣemu, Arfakṣadi, Ṣela,

  8. tí í ṣe ọmọ Serugu, tí í ṣe ọmọ Reu, tí í ṣe ọmọ Pelegi, tí í ṣe ọmọ Eberi, tí í ṣe ọmọ Ṣela.