Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salah

8 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

  1. Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.

  2. Nígbà tí Arfakṣadi pé ọdún márùndínlógójì ni ó bí Ṣela.

  3. Arfakṣadi sì wà láààyè fún ọdún mẹ́tàlénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Ṣela, ó sì bí àwọn ọmọbìnrin àti àwọn ọmọkùnrin mìíràn.

  4. Nígbà tí Ṣela pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Eberi.

  5. Ṣela sì wà láààyè fún ọdún mẹ́tàlénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Eberi tán, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

  6. Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.

  7. Ṣemu, Arfakṣadi, Ṣela,

  8. tí í ṣe ọmọ Serugu, tí í ṣe ọmọ Reu, tí í ṣe ọmọ Pelegi, tí í ṣe ọmọ Eberi, tí í ṣe ọmọ Ṣela.