Skip to content

Serug

6 ẹsẹ · 2 ọmọ ẹbí

A tún mọ̀ ọ́n sí: Saruch

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Serug

  1. Nígbà tí Reu pé ọdún méjìlélọ́gbọ̀n ni ó bí Serugu.

  2. Reu tún wà láààyè lẹ́yìn tí ó bí Serugu fún igba ọdún ó lé méje (207), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mìíràn.

  3. Nígbà tí Serugu pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Nahori.

  4. Serugu sì wà láààyè fún igba ọdún lẹ́yìn tí ó bí Nahori, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

  5. Serugu, Nahori, Tẹra,

  6. tí í ṣe ọmọ Serugu, tí í ṣe ọmọ Reu, tí í ṣe ọmọ Pelegi, tí í ṣe ọmọ Eberi, tí í ṣe ọmọ Ṣela.