Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Roads: From Judea to Galilee, by way of Samaria
Àwọn ẹsẹ nípa From Judea to Galilee, by way of Samaria
Ó fi Judea sílẹ̀, ó sì tún lọ sí Galili.
Òun sì ní láti kọjá láàrín Samaria.
Nígbà náà ni ó dé ìlú Samaria kan, tí a ń pè ní Sikari, tí ó súnmọ́ etí ilẹ̀ oko tí Jakọbu ti fi fún Josẹfu, ọmọ rẹ̀.
Lẹ́yìn ọjọ́ méjì ó sì ti ibẹ̀ kúrò, ó lọ sí Galili.