Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Roads: From Beth-El to Shechem
Àwọn ẹsẹ nípa From Beth-El to Shechem
Wọ́n sì wí pé, “Kíyèsi i ayẹyẹ ọlọ́dọọdún fún Olúwa wà ní Ṣilo ní ìhà àríwá Beteli àti ìhà ìlà-oòrùn òpópó náà tí ó gba Beteli kọjá sí Ṣekemu, àti sí ìhà gúúsù Lebona.”